Yoruba Scheme of Work for JSS1, 2, 3 all Term – Junior Secondary School

Many Secondary School Teacher and Parent whose children are about the get their education in Nigeria are looking for how to download Yoruba Language Scheme of Work for Nigeria Junior Secondary School.

If you are here, then you are at the right page

Scheme of Work on Yoruba Language

Yoruba Scheme of Work for Junior Secondary School

Yoruba is a language of West Africa with over 25 million speakers. It is spoken, among other languages, in Nigeria, Benin, and Togo and traces of it are found among communities in Brazil, Sierra Leone, northern Ghana and Cuba.

Whats other are downloading: SOW for Secondary School in Nigeria

Yoruba Scheme of Work for JSS1 Second Term

List of Topics
ÈDÈ: Àròkô Oníròyìn
ÀSÀ: Àsà Ìgbéyàwó
ÒÝKÀ: Oókanléláàádöta dé ôgörùn-ún (51 – 100)
LÍTÍRÈSÕ
ÈDÈ: Ìsõrí õrõ
LÍTÍRÈSÕ (Ìwé Kíkà): Kíka ìwé lítírèsõ àpilêkô
ÌSÕRÍ ÕRÕ
ERÉ ÌDÁRAYÁ
ÀSÀ: Ètò Ôrõ-Ajé
ÈDÈ: Àkôtö
Àtúnyêwò Êkö
Ìdánwò

Yoruba Scheme of Work for JSS2 First Term
List of Topics
ÈDÈ: Sílébù Èdè Yorùbá
ÀSÀ: Êsìn Ìbílê Yorùbá
LÍTÍRÈSÕ: Àsàyàn Ìwé Ìtàn Àròsô Ôlörõ Geere
ÒÝKÀ: Oókanléláàádöjô dé igba (151 – 200). Kíka owó Náírà
ÈDÈ: Orísirísi Gbólóhùn (Ìhun)
ÈDÈ: Àmì Ohùn
ÀSÀ: Ìranra-çni-löwö
LÍTÍRÈSÕ: Àsàyàn ìwé eré-onítàn
ÀSÀ: Òýkà ôjö àti osù ní ilê Yorùbá
ÈDÈ: Aáyan Ògbufõ
ÀSÀ: Oúnjç Ilê Yorùbá
ÈDÈ: Gbólóhùn
ÀTÚNYÊWÒ ÊKÖ
ÌDÁNWÒ

Yoruba Language Scheme of Work for JSS3 third Term

 List of Topics
ÒWE ÀTI ÀKÀNLÒ ÈDÈ KÉÈKÈÈKÉ
ÈDÈ: Òýkà Yorùbá
ÀŚÀ: Ìtàn Ìśêdálê Yorùbá
LÍTÍRÈŚÕ: Àśàyàn ìwé àyôkà
ÈDÈ: Ìsõrí õrõ
FÓNËTÍÌKÌ: Ìró Èdè Yorùbá
ÀŚÀ: Ìsômôlórúkô
ÈDÈ: Akókò, ìgbà àti ojú ôjö
ÈDÈ: Õrõ Àyálò
ÀŚÀ: Ìkíni
ÈDÈ: Êrô Ayára-bí-àśá (Computer)
ÀTÚNYÊWÒ IŚË
ÌDÁNWÒ

Yoruba Scheme of Work for Junior Secondary School

Below is Third Term week 1-6 Yoruba Language SOW for Junior Secondary School JSS 3.
Teacher can teach with this, while student can used it to study and read ahead.

YORÙBÁ L2 JSS 3 TÁÀMÙ KËTA

ÕSÊ

ORÍ ÕRÕ/ ÀKÓÓNÚ

ÀMÚŚE IŚË

 

1.

ÒWE ÀTI ÀKÀNLÒ ÈDÈ KÉÈKÈÈKÉ

 

ÀKÓÓNÚ

1. Ìtumõ òwe

2. Àbùdá òwe

3. ìwúlò òwe: fún àlàyé, ìkìlõ, ìmõràn, ìbáwí abbl

4. Àkànlò èdè – ìtumõ

5. Oríśi àkànlò èdè pêlú àpççrç

OLÙKÖ

1. Śe àlàyé owe

2. Töka sí àbùdá òwe

3. Śàlàyé ìwúlò òwe pêlú àpççrç

4. Túmõ àkànlò èdè

5. Töka sí oríśi àkànlò èdè kéèkèèké pêlú àpççrç

AKËKÕÖ

1. Tëtí sí àlàyé olùkö

2. Pa òwe tí olùkö kô sí ojú pátákó

3. pa òwe ti ara rç

4. Kô ohun tí olùkö kô sí ojú pátákó sínú ìwé rç

5. Śàlàyé ìyàtõ láàrin òwe àti àkànlò èdè

OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI

1. kádíböõdù tí a kô òwe àti àkànlò èdè sí.

2. káàdì pélébé pélébé tí a kô òwe àti àkànlò èdè sí

2.

ÈDÈ: Òýkà Yorùbá

 

ÀKÓÓNÚ IŚË

1. Àtúnyêwò òýkà láti oókan dé êëdëgbêta (1-500)

2. ka òýkà láti oókan dé êëdëgbêta

3. Da fígõ àwôn òýkà náà mõ.

OLÙKÖ

1. kô òýkà sí ara pátákó

2. śe àlàyé ìlànà òýkà

3. śe ìdánwò fún akëkõö lórí òýkà náà.

AKËKÕÖ

1. Da àwôn òýkà tí olùkö kô sí ara pátákó kô sínú ìwé rç

2. Tëtí sí àlàyé olùkö

3. Śe ìdánwò tí olùkö pèsè ní kíláásì

OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI

1. kádíböõdù

2. káàdì pélébé pélébé

3.

ÀŚÀ: Ìtàn Ìśêdálê Yorùbá

 

ÀKÓÓNÚ IŚË

1. Ìtêsíwájú ìtàn ìśêdálê Yorùbá

2. Àwôn ômô Õkànbí

3. Àwôn ôba ilê Yorùbá àti orúkô oyè wôn

4. Êyà Yorùbá àti êka èdè wôn

OLÙKÖ

1. Śe àlàyé ìtàn ìśêdálê Yorùbá àti bí wôn śe tan káàkiri

2. Töka sí àwôn ôba Yorùbá àti orúkô oyè wôn

3. Dárúkô àwôn ìlú Yorùbá àti êka èdè tí wön ń sô

AKËKÕÖ

1. Dárúkô díê lára àwôn agbègbè tí êyà Yorùbá tàn dé

2. Dárúkô àwôn ôba Yorùbá yàtõ sí ti olùkö

3. Sô díê lára àwôn ìlú Yorùbá àti êka èdè wôn

4. Tëtí sí àlàyé olùkö.

OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI

1. Máàpù ilê Áfíríkà àti ilê Marubaawa

2. Máàpù Nàìjíríà àti ilê Yorùbá

4.

LÍTÍRÈŚÕ: Àśàyàn ìwé àyôkà

 

ÀKÓÓNÚ IŚË

1. Àtúnyêwò àwôn àśàyàn ìwé ìtàn àròsô ôlörõ geere, ewì àti eré-onítàn

2. ìtàn inú ìwé ní sókí

3. Êdá ìtàn

4. Ìfìwàwêdá

5. ibùdó ìtàn

6. Àhunpõ ìtàn  

7. kókó õrõ tó jçyô

OLÙKÖ

1. Darí akëkõö láti sô ní sókí ìtàn náà

2. Śe àlàyé ní kíkún lórí êdá ìtàn, ìfìwàwêdá, ibùdó ìtàn, kókó õrõ

3. Darí ìjíròrò àti eré ní kíláásì

AKËKÕÖ

1. Ka ìtàn àròsô

2. Tëtí sí àlàyé olùkö kí ó sì śe àkôsílê rê.

3. Béèrè ìbéèrè nípa ohun tí kò bá yé wôn

4. Sô ní sókí ohun tí  ìwé dálé lórí

5. kópa nínú ìśeré tí olùkö darí

OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI

1. ìwé tí a yàn

2. ohun èlò ìśeré

3. orí ìtàgé

4. Àwòrán àfihàn ìśêlê àti êdá ìtàn eré.

5.

ÈDÈ: Ìsõrí õrõ

 

ÀKÓÓNÚ IŚË

1. Ìtêsíwájú lórí ìsõrí õrõ

2. Dárúkô àwôn ìsõrí õrõ Yorùbá: õrõ-orúkô, õrõ-àpönlé, õrõ-aröpò orúkô, õrõ-ìśe, õrõ-àpèjúwe, õrõ-atökùn, õrõ-àsopõ

3. Àlàyé kíkún lórí ipò àti iśë wôn nínú gbólóhùn

OLÙKÖ

1. Śe àlàyé lórí ipò àti iśë õkõõkan nínú gbolohun

2. Śe õpõlôpõ àpççrç lórí õkõõkan fún akëkõö

3. Darí akëkõö láti śe àpççrç tirê.

AKËKÕÖ

1. Tëtí sí àlàyé olùkö

2. Kô àwôn àpççrç tí olùkö śe sínú ìwé

3. Śe àwôn àpççrç tìrç lábë ìdarí olùkö

OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI

1. kádíböõdù

2. káàdì pélébé pélébé

Download Now SOW for Yoruba Language

How to Download JSS 1-3 Yoruba Scheme of Work

To get the complete Yoruba Scheme of Work in PDF Format, Call or whatsapp me on 08051311885 on how to obtain your copy.

Please Note, it is not Free.

Please Take Note:
The scheme of work is in PDF soft copy format.
It can be view and read using a smart mobile phone or personal computer (pc)
It can be printed out into hard copy.
It is not free (do not chat me up if your intention is to beg for it)
It cost a token.

Mode of Delivery
After payment, it will be sent to your email address or whatsapp

Other Available Products

Lesson Note and Exam Questions for Primary to Senior Secondary School

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *